Ẹgbẹ WordPress Yoruba ni ipade…

Ẹgbẹ WordPress Yoruba ni ipade ni gbogbo Ọjọ Aiku (Sunday) laago mejo si mesan ale (8:00 PM – 9:00 PM), lori ikanni #ipade ti Slack WordPress Yoruba tabi nipasẹ apejọ fidio.

A le ṣe atunṣe si Ofin yii ti isinmi (holiday) ba wa, tabi fun irorun ti gbogbo omo ẹgbẹ.

Maṣe gbagbe lati ṣe akiyesi awọn ọjọ wọnyi ninu kalẹnda rẹ ati pe ti o ko ba raye ni asiko naa, ranti lati se ayewo ipade na ninu ikanni #ipade lori slack.

📌 Awọn ipade wa ni sisi fun ẹnikẹni ti o nifẹ lati tumọ WordPress si Yoruba.