Ẹ̀dà kan pẹ̀lú style
Jẹ́ kí àwọn èrò rẹ di gidi lọ́nà tó rọrùn pẹ̀lú WordPress 6.4. Ṣàwárí theme àkọ́kọ́ tuntun tó ní ọ̀pọ̀ apá àti àkójọpọ̀ àwọn ìlọsíwájú láti fún gbogbo ìgbésẹ̀ ìrìnàjò ìṣẹ̀dá rẹ ní agbára.


Ẹ kú àbọ̀ sí
Twenty Twenty-Four
Twenty Twenty-Four jẹ́ theme àkọ́kọ́ tó lẹ́wà, tó sì ṣeé lò lọ́pọ̀lọpọ̀, tí a ṣe pẹ̀lú àwọn lílo ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ọkàn, láti ọ̀dọ̀ àwọn akọ̀wé àti àwọn oníṣẹ́ ọnà dé àwọn oníṣòwò. Àkójọpọ̀ pattern rẹ̀ tó gbòòrò àti àǹfààní rẹ̀ sọ ọ́ di àṣàyàn tó dára jùlọ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àìní ìṣẹ̀dá àti ìṣòwò.
Bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìkọ̀wé rẹ
Ṣàwárí àkójọpọ̀ pattern Twenty Twenty-Four fún ojú ìwé ìbẹ̀rẹ̀, àwọn post kọ̀ọ̀kan, àti àwọn template àkójọ. Lò wọ́n gẹ́gẹ́ bíi ìbẹ̀rẹ̀ láti ṣẹ̀dá blog àrà ọ̀tọ̀ tó bá style rẹ mu.
Ṣàfihàn iṣẹ́ rẹ
Fi àkókò àti agbára pamọ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ portfolio, testimonial, àti àwọn pattern ẹgbẹ́ tí a ṣètò láti ṣàfihàn àwọn iṣẹ́ àkànṣe ìṣẹ̀dá rẹ àti láti fún àwọn oníbàárà rẹ tó ṣeéṣe ní ìwúrí.
Ní ìrírí ṣíṣàtúnṣe ìkànnì tó dára jù lọ
Twenty Twenty-Four theme ṣàkópọ̀ àwọn àǹfààní Site Editor tuntun àti àwọn ohun èlò ìṣẹ̀dá. Lo àǹfààní àìlẹ́gbẹ́ ti kíkọ́ pẹ̀lú àwọn block láti mú iṣẹ́ àkànṣe rẹ tó kàn wá sí ìgbésí ayé.
Ṣeéṣe láti ṣe àtúnṣe pátápátá
Ṣe àtúnṣe àwọn àwọ̀, typography, àti àwọn template láti sọ theme náà di tìrẹ pàtó.
Ó yára, ó sì ń ṣiṣẹ́ dáadáa
A ti ṣe Twenty Twenty-Four dáadáa kó lè yára ṣiṣẹ́.
Ìṣẹ̀dá tó bá ẹ̀rọ mu
Rí i dájú pé ìkànnì rẹ dára lórí gbogbo ẹ̀rọ.

Ṣàwárí àwọn pattern tó ju 35 lọ tí a ṣe pẹ̀lú ìṣọ́ra
Lo àǹfààní àkójọpọ̀ pattern àti template ọlọ́rọ̀ ti theme náà láti kọ àwọn ojú ìwé irú èyíkéyìí—kí o sì mú ìlànà kíkọ́ ìkànnì rẹ rọrùn.
Jẹ́ kí ìkọ̀wé rẹ sàn
Àwọn ìlọsíwájú tuntun rí i dájú pé ìrírí ìṣẹ̀dá àkóónú rẹ rọrùn, pẹ̀lú àwọn ọ̀nà àbùjá keyboard tuntun, àwọn àtòjọ tó gbọ́n jù, àti ìṣàkóso tó dára sí i lórí àwọn ètò ìsopọ̀ rẹ. Ìrírí toolbar tó báramu fún àwọn block Navigation, List, àti Quote rí i dájú pé ààyè sí àwọn àṣàyàn ohun èlò tí o fi ń ṣiṣẹ́ wà ní ìṣètò.
Ṣe púpọ̀ sí i pẹ̀lú Command Palette
Wá ohun tí o nílò ní kíákíá, ṣe àwọn iṣẹ́ lọ́nà tó múná dóko, kí o sì mú ìṣàn iṣẹ́ kíkọ́ rẹ yára pẹ̀lú Command Palette tó lágbára jù.
- Gbádùn ìrísí tuntun
- Ṣe àwọn ìgbésẹ̀ block kan pàtó
- Jàǹfààní látinú orúkọ àṣẹ (command label) tó ti sunwọ̀n sí i


Ṣeré pẹ̀lú àwọn àwòrán ẹ̀yìn tuntun nínú àwọn Group block fún àwọn ìṣẹ̀dá àrà ọ̀tọ̀

Jẹ́ kí àwọn àwòrán rẹ yọrí
Mú àǹfààní lightbox ṣiṣẹ́ láti jẹ́ kí àwọn àlejò ìkànnì rẹ gbádùn àwọn àwòrán ìbánisọ̀rọ̀ ojú ìbòjú kíkún nígbà tí wọ́n bá tẹ ẹ́. Lò ó ní gbogbogbòò tàbí sí àwọn àwòrán kan pàtó láti ṣe àtúnṣe ìrírí wíwo.

Dán an wò nípa títẹ àwọn àwòrán tó wà nísàlẹ̀




Ìfihàn
Block Hooks
Pẹ̀lú Block Hooks, àwọn developer lè fi àwọn dynamic block sí àwọn ipò àkóónú kan pàtó ládàáṣe, ní sísọ extensibility àwọn block theme di ọlọ́rọ̀ nípasẹ̀ àwọn plugin. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kà á sí ohun èlò developer, ohun yìí ni a ṣe láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ìfẹ́ rẹ, ó sì fún ọ ní ìṣàkóso pátápátá láti fi kún un, yọ kúrò, àti láti ṣe àtúnṣe àwọn block tí a fi sí ládàáṣe gẹ́gẹ́ bí àìní rẹ.

Àti púpọ̀ sí i

Tún àwọn Group block sọ lórúkọ
Ṣètò àwọn orúkọ àdáṣe fún àwọn Group block láti ṣètò àti láti fi ìyàtọ̀ sáàárín àwọn agbègbè àkóónú rẹ lọ́nà tó rọrùn.
Fi àwọn bọ́tìnì navigation kún un
Fi àwọn button sínú navigation menu rẹ láti darí àwọn àlejò sí call-to-action. Báyìí ó ṣeé ṣe láìkọ ìlà code kan.
Wo ìwò ṣáájú àwọn àwòrán nínú List View
Rí àwọn àwòrán ojú ìwé rẹ, kó o sì mọ ibi tí wọ́n wà ní ìwò kan pẹ̀lú gallery tuntun àti ìwò ṣáájú àwòrán nínú List View.
Ṣètò aspect ratio fún àwọn àyè àwòrán (placeholder)
Jẹ́ kí àwọn layout dúró bákan náà pẹ̀lú aspect ratio fún àwọn àyè àwòrán (placeholder), kí ìwọ̀n tó o fẹ́ lè wà bó o ṣe ń fa àwọn àwòrán sínú wọn.
Pín àwọn pattern sí ìsọ̀rí kó o sì ṣe filter wọn
Ṣètò àwọn pattern rẹ pẹ̀lú àwọn custom categories. Ṣàwárí filter tó gbòòrò nínú apá Patterns ti inserter láti wá gbogbo wọn lọ́nà tó túbọ̀ ṣe é gbọ́ yé.
Pín àwọn pattern kaakiri àwọn ìkànnì
Ṣé o nílò láti lo àwọn custom pattern rẹ lórí ìkànnì mìíràn? Ó rọrùn. Gbé wọn wọlé tàbí jáde gẹ́gẹ́ bí àwọn file JSON láti pattern view ti Site Editor.

Performance
WordPress 6.4 ní àwọn àtúnṣe tó ní í ṣe pẹ̀lú performance tó ju 100 lọ fún ìrírí tó yára àti tó ṣiṣẹ́ dáadáa. Àwọn ìlọsíwájú pàtàkì gbájú mọ́ ìyára ṣíṣí template fún àwọn theme, lílo àwọn ọgbọ́n ìgbéjáde script “defer” àti “async” nínú core, àwọn block, àti àwọn theme, àti àwọn iṣẹ́ tuntun láti mú àwọn àṣàyàn autoloaded sunwọ̀n sí i.
Accessibility
Gbogbo ẹ̀dà ti pinnu láti jẹ́ kí WordPress ṣeé wọlé sí fún gbogbo ènìyàn. 6.4 mú àwọn ìlọsíwájú List View àti ìtìlẹ́yìn aria-label wá fún Navigation block, láàárín àwọn ohun pàtàkì mìíràn. Ojú ìṣàkóso admin ní àwọn ìlọsíwájú sí ìgbékalẹ̀ bọ́tìnì, àyíká àwọn nǹkan inú àtòkọ “Add New”, àti àwọn ìkéde Site Health.
Ọpẹ́ fún àwọn
olùkópa tó ju 600 lọ tí wọ́n ṣe ẹ̀dà yìí
Wo gbogbo àwọn olùkópa
6adminit · Aaron D. Campbell · Aaron Jorbin · Aaron Robertshaw · aayusha · Abha Thakor · Abid Omar · Adam Silverstein · Adam Zieliński · Adhun Anand · admcfajn · Adrian Duffell · ahardyjpl · Ahmed Hussein · Ahmed Kabir Chaion · ajakaroth · Aki Hamano · Akihiro Harai · Akira Tachibana · Akshaya Rane · Al-Amin Firdows · Alain Schlesser · Albert Juhé Lluveras · Alex Concha · Alex King · Alex Lende · Alex Stine · Alexandre Buffet · Alisha Bajracharya · Allison Tarr · Alvi Tazwar · amedv · Ana Cirujano · Anand Upadhyay · Anders Norén · Andrea Fercia · Andrei Draganescu · Andrew Hayward · Andrew Hutchings · Andrew Nacin · Andrew Ozz · Andrew Serong · Andrew Wilder · André Maneiro · Andy Fragen · Andy Peatling · Angela Jin · Anh Tran · Ankit Gade · Ankit K Gupta · Ankit Panchal · Anna · Anne McCarthy · Anne-Mieke Bovelett · anphira · Anthony Burchell · Anton Plauche · Anton Timmermans · Anton Vlasenko · Anveshika Srivastava · archon810 · arena · Ari Stathopoulos · Arnab Mondal · Artemio Morales · Arthur Chu · asafm7 · askdesign · Aslam Doctor · Aurooba Ahmed · Austin Ginder · Ayesh Karunaratne · azharckra · Balu B · bangank36 · barbmiller · Barry · Bart Kalisz · Basilis Kanonidis · Beatriz Fialho · behoney · ben · Ben Dwyer · Ben Greeley · Ben Hansen · Benjamin Intal · Benjamin Zekavica · benjaminknox · Benoit Chantre · Bernhard Reiter · Bhrugesh Bavishi · Bijay Yadav · Bimal Shrestha · Binsaifullah · Biplav · Birendra Dhami · Birendra Maharjan · Birgit Olzem · Birgit Pauli-Haack · bobbingwide · bonger · bookwyrm · Boone Gorges · Boro Sitnikovski · brad hogan · Brad Jorsch · Bradley Jacobs · Brandon Kraft · Brandon Vreeman · Brian Alexander · Brian Gardner · Brian Haas · Brooke · Brooke. · Bud Kraus · Caleb Burks · Calvin Alkan · Carlo Cannas · Carlos Bravo · Carlos G. P. · Carolina Nymark · Cathi Bosco · ceer · cenkdemir · Chad Chadbourne · chased@si.edu · Chintan hingrajiya · Chip Bennett · Chloé Bringmann · Chris Desrochers · Chris Runnells · chriscct7 · codersantosh · Colin Stewart · Corey Worrell · Courtney Patubo Kranzke · Courtney Robertson · Crisoforo Gaspar · crstauf · Csaba (LittleBigThings) · Cupid Chakma · cybeardjm · Cyberchicken · Daisuke Takahashi · Dajeema Rai · Damon Cook · Damon Sharp · Dan Tovbein · Daniel Bachhuber · Daniel Käfer · Daniel Richards · Daniele Scasciafratte · Danielle Zarcaro · danieltj · Danny Dudzic · Darin Kotter · darkfate · Darren Ethier (nerrad) · Darshit Rajyaguru · Dave Loodts · Dave Ryan · dave03 · David Arenas · David Baumwald · David Biňovec · David Calhoun · David E. Smith · David Favor · David Herrera · David Smith · Dawid Urbanski · daxelrod · De Belser Arne · Dean Sas · Dee Teal · Deepak Vijayan · Denis Žoljom · Dennis Snell · Derek Blank · Derrick Tennant · Devan Ferguson · Dharmesh Patel · Dhrumil Kumbhani · Dhruvi Shah · Diane Co · Dilip Bheda · Dimitris Mitsis · Dion Hulse · DJ · dj.cowan · Dominik Schilling · doughamlin · Drew Jaynes · Earle Davies · Ebonie Butler · Edi Amin · Edward Caissie · Ehtisham Siddiqui · Ella van Durpe · Ellen Bauer · emailjoey · Emerson Maningo · Emily Clarke · Emily Leffler Schulman · emirpprime · enodekciw · Enrico Battocchi · Erik · Esrat Sultana Popy · Estela Rueda · Fabian Kaegy · Fabian Todt · Fabio Rubioglio · Faisal Alvi · Felipe Elia · Felix Arntz · Femy Praseeth · Filippo D'Angelo · floydwilde · FolioVision · Francesca Marano · Frank Laszlo · Fredde Battel · fzhantw · Gabriel Koen · Garrett Hyder · Gary Cao · Gary Pendergast · Gennady Kovshenin · George Hotelling · George Mamadashvili · Gerardo Pacheco · Gio Lodi · Glen Davies · Gnanasekaran Loganathan · Gopal Krishnan · gpotter · Grant M. Kinney · Greg Ross · Greg Ziółkowski · gregfuller · Guss77 · Gustavo Bordoni · hanneslsm · Hanzala Taifun · Hareesh S · Harsh Gajipara · Hasanuzzaman Shamim · Haz · Helen Hou-Sandi · Hemant Tejwani · Hit Bhalodia · hlunter · Howdy_McGee · Huzaifa Al Mesbah · Héctor Prieto · Ian Dunn · Incursa Designs · Isabel Brison · itecrs · Ivan Tsoma · jaimieolmstead · Jakaria Istauk · Jake Goldman · Jake Spurlock · James Hunt · James Janco · James Koster · James Roberts · james0r · Jamie McHale · Jamie Perrelet · Jamie VanRaalte · jane · Jarda Snajdr · Jari Vuorenmaa · Jarko Piironen · Jason Adams · Jason Cosper · Jason Crist · jastos · Jean-Baptiste Audras · Jeff Bowen · Jeff Chi · Jeff Everhart · Jeff Ong · jeffikus · Jeffrey Paul · jeflopo · Jeremy Felt · Jeremy Herve · Jeremy Yip · jeryj · Jesin A · Jessica Duarte · Jessica Goddard · Jessica Lyschik · Jick · Jip Moors · jivygraphics · Joe Dolson · Joe Hoyle · Joe McGill · Joen Asmussen · John Blackbourn · John Hooks · John James Jacoby · John Regan · Jon Brown · Jon Cave · Jonathan Desrosiers · Jonny Harris · Jono Alderson · Joona · Joost de Valk · joppuyo · JordanPak · jordesign · Jorge Costa · Joseph G. · Josepha Haden · joshcanhelp · joshuatf · JR Tashjian · Juanfra Aldasoro · JuanMa Garrido · Juliette Reinders Folmer · Justin Tadlock · Jyolsna J E · K M Ashikur Rahman · K. Adam White · KafleG · Kai Hao · Kalmang · Kalpesh · Kamrul Hasan · Karlijn Bok · Karma samir · Karol Manijak · Karthik Thayyil · kawsaralameven · Keanan Koppenhaver · Kelly Choyce-Dwan · Kevin Fodness · Kevin Miller · Kevin Taron · Kharis Sulistiyono · khleomix · Khokan Sardar · Kim Coleman · Kira Song · Kishan Jasani · kkmuffme · Koji Kuno · Konstantin Kovshenin · Konstantin Obenland · Kopila Shrestha · Krupal Panchal · Kylen Downs · Labun Chemjong · Lance Willett · LarryWEB · lastsplash (a11n) · lau@mindproducts.com.au · launchinteractive · Laura Adamonis · Laura Byrne · laurelfulford · Lauren @ Once Coupled · Lax Mariappan · Laxmikant Bhumkar · Lee Willis · Lena Morita · LeTraceurSnork · Liam Gladdy · Linkon Miyan · Linnea Huxford · Lloyd Budd · Lovekesh Kumar · Luigi Teschio · Luis Felipe Zaguini · Luis Herranz · Luke Cavanagh · lunaluna · lyndauwp · Maciej Ma?kowiak · madejackson · Madhu Dollu · Madhu Dollu · Maggie Cabrera · Mahbub Hasan Imon · Mahrokh · Mai · Maja Benke · maltfield · Manesh Timilsina · manfcarlo · Manzoor Wani · marcelle42 · Marcelo de Moraes Serpa · Marcio Duarte · Marco Ciampini · Marco Pereirinha · Marcoevich · margolisj · Marin Atanasov · Mario Santos · Marius L. J. · Mark Jaquith · Marko Ivanovic · Marta Torre · Martijn van der Klis · martin.krcho · Mary Baum · Masoud Najjar Khodabakhsh · mathsgrinds · Matias Benedetto · Matias Ventura · Matt Keys · Matt Watson · Matthaus Klute · Matthew Eppelsheimer · Matthew Farlymn · Matthew Haines-Young · matthewjho · maurodf · Maxwell Morgan · maysi · Md Hasanur Rahman Shahin · Md Monir Hossain · meagan hanes · Mehedi Hassan · Meher Bala · Mel Choyce-Dwan · mer00x · merel1988 · meta4 · Michael Arestad · Michael Burridge · Michael Showes · Michalooki · Michał Czapliński · Michelle Blanchette · Michelle Frechette · Michi91 · Miguel Fonseca · Mikael Korpela · Mike Jolley · Mike McAlister · Mike Schinkel · Mike Straw · Mikin Chauhan · Milen Petrinski Ìtumọ̀ Yorùbá: – Gonzo · mimi · mitchellaustin · Mrinal Haque · mrwweb · Muhammad Arslan · Muhibul Haque · mujuonly · Mukesh Panchal · Mumtahina Faguni · Mushfiq Poran · Mushrit Shabnam · Myles Taylor · Nalini Thakor · nandhuraj · Nazgul · Nazmul Sabuz · Neil Hainsworth · nendeb · Nick Diego · Nicolas Juen · Nicole Furlan · nicomollet · nidhidhandhukiya · Niels Lange · Nihar Ranjan Das · Nik Tsekouras · Nilo Velez · Nirav Sherasiya · Nitesh Das · Nithin John · Nithin SreeRaj · Noah Allen · Nyasha · ockham · Ohia · okat · Olga Gleckler · Oliver Campion · OllieJones · Paal Joachim Romdahl · pannelars · partyfrikadelle · Pascal Birchler · Paul Biron · Paul Kevan · pavelevap · Pedro Mendonça · pentatonicfunk · Pete Nelson · Peter Wilson · petitphp · Petros P · Petter Walbø Johnsgård · Phill · Pieterjan Deneys · piyushdeshmukh · Plugin Devs · Pooja Bhimani · Pooja Derashri · Pooja Killekar (Muchandikar) · pranavjoshi · Prashant · Presskopp · r-c · rabmalin · Rajin Sharwar · Ramon Ahnert · Ramon Corrales · Ramon James · rawrly · rebasaurus · Rebekah Markowitz · Remy Perona · ren · Renatho · Rene Hermenau · Reyes Martínez · Riad Benguella · Rian Rietveld · Rich Tabor · Robert Anderson · Robert O'Rourke · robinwpdeveloper · robpetrin · Rolf Allard van Hagen · Ryan Duff · Ryan McCue · Ryan Neudorf · Ryan Welcher · Sagar Tamang · Sajjad Hossain Sagor · Sakib Mohammed · Sal Ferrarello · samba45 · Sampat Viral · Samuel Wood (Otto) · Sarah Norris · Sarah Williams · Sarath AR · Satish Prajapati · saulirajala · saxonfletcher · Scott Kingsley Clark · Scott Reilly · Scott Taylor · Scout James · scribu · Sergey Biryukov · Sergio Scabuzzo · Seth Rubenstein · Shail Mehta · shawfactor · Shawn Hooper · Shilo · Shiva Shanker Bhatta · shresthaaman · Shubham Sedani · Simon Dowdles · Siobhan · Siobhan Bamber · Smit Rathod · Sofia Shendi · Sonia Gaballa · SourceView · Spenser Hale · Stephanie Walters · Stephen Bernhardt · Stephen Edgar · Steve Erdelyi · Steve Jones · Subodh Sunuwar · Subrata Sarkar · Suji K Chandran · Sumi Subedi · Sumit Bagthariya · Sumit Singh · Sunita Rai · suprsam · syamraj24 · Sybre Waaijer · Synchro · Sé Reed · Sérgio Gomes · Sören Wünsch · Taco Verdonschot · Tahmid ul Karim · Tahmina Jahan · Takayuki Miyoshi · Tammie Lister · Tanvirul Haque · Teddy Patriarca · Teja Dev · thinkluke · Thomas Patrick Levy · tibbsa · Tiffany Bridge · Tim Nolte · timdix · Timothy Jacobs · Tinjure20 · tmatsuur · Tobias Bäthge · tobifjellner (Tor-Bjorn “Tobi” Fjellner) · Tom · Tom Cafferkey · Tom H · Tom J Nowell · tomluckies · Tomoki Shimomura · tomsommer · Tony G · Tonya Mork · Toro_Unit (Hiroshi Urabe) · Torsten Landsiedel · toscho · Trinisha · Trisha Salas · tristanleboss · TV productions · Ugyen Dorji · Ulrich · Umesh Balayar · upadalavipul · Utsav tilava · valentindu62 · Valerie Blackburn · Vicente Canales · Vijayan · Viktor Szépe · Vipul Ghori · vivekawsm · vortfu · Vraja Das · webashrafians · WebMan Design | Oliver Juhas · Weston Ruter · WHSajid · Will Earnhardt · Will Skora · Willington Vega · Winstina · winterstreet · WraithKenny · wyrfel · Yoseph Tamang · Yui · Zunaid Amin · Česlav Przywara